Ojú Kòkòrò (2016)

- Directed by
- Dare Olaitan
- Country
- Nigeria
- Runtime
- 1h 50m

The catalogue in 3D
The film shelves have a room of their own that you can walk around in. The cat behind the counter is the AI Catbot, and they pick real films from the same catalogue when you tell them what you feel like watching. Nothing is for sale, here or in there. Go in from here and this film is already out on the counter, with more like it waiting on the shelf next to it.
How it feels
A group of employees plot to rob their own boss. Their plans go wrong when multiple other criminals with the same idea show up.
chaoticfunnygreedyfast-pacedsuspensefuldarkly comictense
What happens
Ojú Kòkòrò: Greed, jẹ́ eré sinimá agbéléwò tí ó jẹ́ àkójọ àwọn eré crime-heist comedy film tí wọ́n gbé jáde ní ọdún 2016, tí àwọn gbajúmọ̀ òṣèré bíi : Wale Ojo, Tope Tedela, Charles Etubiebi, Seun Ajayi, Shawn Faqua, Ali Nuhu, Somkele Iyamah, Emmanuel Ikubese àti Afeez Oyetoro ti kópa. Dáre Ọláìtán ni ó darí eré yí nígbà tí Olufemi D. Ogunsanwo jẹ́ olùgbéré náà jáde. Olaitan ni ó ke eré yí ní ọdún 2014, eré yí ni ó jẹ́ akọ́kọ́ eré tí yóò kọ́kọ́ kọ parí tí yóò si di gbígbé jáde Wọ́n ṣe ṣe agbékalẹ̀ eré náà ní ìlànà tí ó fi bá àkókò kọ̀ọ̀kan mu tí ó sì mú àwọn òṣèré ati ònwòran lọ́kàn. Wọ́n gbé eré náà jáde ní ọjọ́ Kẹtàdínlógún oṣù Kẹta ọdún 2014. Olaitan wrote Ojukokoro in 2014. (from Wikipedia, CC BY-SA)
More like this
Ojukokoro (2016)
The CEO (2016)
Brother Jekwu (2016)
Just Not Married (2016)
The Boss is Mine (2016)
A Trip to Jamaica (2016)
Suru L'ere (2016)
Green White Green (2016)- More like this film, on a shelf you can walk up to.It's the lit case on the top shelf.